1. Sam 28:22 YCE

22 Njẹ, nisisiyi, emi bẹ ọ, gbọ́ ohùn iranṣẹbinrin rẹ, emi o si fi onjẹ diẹ siwaju rẹ; si jẹun, iwọ o si li agbara, nigbati iwọ ba nlọ li ọ̀na.

Ka pipe ipin 1. Sam 28

Wo 1. Sam 28:22 ni o tọ