1. Sam 28:23 YCE

23 Ṣugbọn on kọ̀, o si wipe, Emi kì yio jẹun. Ṣugbọn awọn iranṣẹ rẹ̀, pẹlu obinrin na si rọ̀ ọ; on si gbọ́ ohùn wọn. O si dide kuro ni ilẹ, o si joko lori akete.

Ka pipe ipin 1. Sam 28

Wo 1. Sam 28:23 ni o tọ