1. Sam 3:5 YCE

5 O si sare tọ Eli, o si wipe, Emi nĩ; nitori ti iwọ pè mi. On wipe, emi kò pè: pada lọ dubulẹ. O si lọ dubulẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 3

Wo 1. Sam 3:5 ni o tọ