1. Sam 3:6 YCE

6 Oluwa si tun npè, Samueli. Samueli si dide tọ Eli lọ, o si wipe, Emi nĩ; nitoriti iwọ pè mi. O si da a lohun, emi kò pè, ọmọ mi; padà lọ dubulẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 3

Wo 1. Sam 3:6 ni o tọ