1. Sam 6:2 YCE

2 Awọn Filistini si pe awọn alufa ati awọn alasọtẹlẹ, wipe, Awa o ti ṣe apoti Oluwa si? sọ fun wa ohun ti awa o fi rán a lọ si ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 6

Wo 1. Sam 6:2 ni o tọ