1. Sam 7:8 YCE

8 Awọn ọmọ Israeli si wi fun Samueli pe, Máṣe dakẹ ati ma ke pe Oluwa Ọlọrun wa fun wa, yio si gbà wa lọwọ́ awọn Filistini.

Ka pipe ipin 1. Sam 7

Wo 1. Sam 7:8 ni o tọ