1. Sam 8:20 YCE

20 Ani awa o si dabi gbogbo orilẹ-ède; ki ọba wa ki o si ma ṣe idajọ wa, ki o si ma ṣaju wa, ki o si ma ja ogun wa.

Ka pipe ipin 1. Sam 8

Wo 1. Sam 8:20 ni o tọ