Joṣ 1:2 YCE

2 Mose iranṣẹ mi kú; njẹ iwọ, dide, gòke Jordani yi, iwọ, ati gbogbo enia yi, si ilẹ ti mo fi fun wọn, ani fun awọn ọmọ Israeli.

Ka pipe ipin Joṣ 1

Wo Joṣ 1:2 ni o tọ