Joṣ 10:20 YCE

20 O si ṣe, nigbati Joṣua ati awọn ọmọ Israeli pa wọn ni ipakupa tán, titi a fi run wọn, ti awọn ti o kù ninu wọn wọ̀ inu ilu olodi lọ,

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:20 ni o tọ