Joṣ 10:33 YCE

33 Nigbana ni Horamu ọba Geseri gòke lati ràn Lakiṣi lọwọ; Joṣua si kọlù u ati awọn enia rẹ̀, tobẹ̃ ti kò fi kù ẹnikan silẹ fun u.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:33 ni o tọ