Joṣ 10:8 YCE

8 OLUWA si wi fun Joṣua pe, Má ṣe bẹ̀ru wọn: nitoriti mo ti fi wọn lé ọ lọwọ; ki yio sí ọkunrin kan ninu wọn ti yio le duro niwaju rẹ.

Ka pipe ipin Joṣ 10

Wo Joṣ 10:8 ni o tọ