Joṣ 11:11 YCE

11 Nwọn si fi oju idà pa gbogbo ọkàn ti mbẹ ninu rẹ̀, nwọn run wọn patapata: a kò kù ẹnikan ti nmí silẹ: o si fi iná kun Hasoru.

Ka pipe ipin Joṣ 11

Wo Joṣ 11:11 ni o tọ