Joṣ 11:4 YCE

4 Nwọn si jade, awọn ati gbogbo ogun wọn pẹlu wọn, ọ̀pọlọpọ enia, bi yanrin ti mbẹ li eti okun fun ọ̀pọ, ati ẹṣin ati kẹkẹ́ pipọ̀pipọ.

Ka pipe ipin Joṣ 11

Wo Joṣ 11:4 ni o tọ