8 Ni ilẹ òke, ati ni ilẹ titẹju, ati ni pẹtẹlẹ̀, ati li ẹsẹ̀-òke, ati li aginjù, ati ni Gusù; awọn Hitti, awọn Amori, ati awọn ara Kenaani, awọn Perissi, awọn Hifi, ati awọn Jebusi:
9 Ọba Jeriko, ọkan; ọba Ai, ti o wà lẹba Beti-eli, ọkan.
10 Ọba Jerusalemu, ọkan; ọba Hebroni, ọkan;
11 Ọba Jarmutu, ọkan; ọba Lakiṣi, ọkan;
12 Ọba Egloni, ọkan; ọba Geseri, ọkan;
13 Ọba Debiri, ọkan; ọba Gederi, ọkan;
14 Ọba Horma, ọkan; ọba Aradi, ọkan;