Joṣ 13:29 YCE

29 Mose si fi ilẹ-iní fun àbọ ẹ̀ya Manasse: o si jẹ́ ti àbọ ẹ̀ya awọn ọmọ Manasse gẹgẹ bi idile wọn.

Ka pipe ipin Joṣ 13

Wo Joṣ 13:29 ni o tọ