Joṣ 13:9 YCE

9 Lati Aroeri lọ, ti mbẹ leti afonifoji Arnoni, ati ilu ti mbẹ lãrin afonifoji na, ati gbogbo pẹtẹlẹ̀ Medeba titi dé Diboni;

Ka pipe ipin Joṣ 13

Wo Joṣ 13:9 ni o tọ