Joṣ 16:10 YCE

10 Nwọn kò si lé awọn ara Kenaani ti ngbé Geseri jade: ṣugbọn awọn ara Kenaani joko lãrin Efraimu titi di oni yi, nwọn si di ẹrú lati ma sìnru.

Ka pipe ipin Joṣ 16

Wo Joṣ 16:10 ni o tọ