Joṣ 16:5 YCE

5 Àla awọn ọmọ Efraimu gẹgẹ bi idile wọn li eyi: ani àla ilẹ-iní wọn ni ìha ìla-õrùn ni Atarotu-adari, dé Beti-horoni òke;

Ka pipe ipin Joṣ 16

Wo Joṣ 16:5 ni o tọ