Joṣ 18:10 YCE

10 Joṣua si ṣẹ́ keké fun wọn ni Ṣilo niwaju OLUWA: nibẹ̀ ni Joṣua si pín ilẹ na fun awọn ọmọ Israeli gẹgẹ bi ipín wọn.

Ka pipe ipin Joṣ 18

Wo Joṣ 18:10 ni o tọ