Joṣ 18:20 YCE

20 Jordani si ni àla rẹ̀ ni ìha ìla-õrùn. Eyi ni ilẹ-iní awọn ọmọ Benjamini, li àgbegbe rẹ̀ kakiri, gẹgẹ bi idile wọn.

Ka pipe ipin Joṣ 18

Wo Joṣ 18:20 ni o tọ