Joṣ 2:2 YCE

2 A si sọ fun ọba Jeriko pe, Kiyesi i, awọn ọkunrin kan ninu awọn ọmọ Israeli dé ihinyi li alẹ yi lati rìn ilẹ yi wò.

Ka pipe ipin Joṣ 2

Wo Joṣ 2:2 ni o tọ