Joṣ 20:6 YCE

6 On o si ma gbé inu ilu na, titi yio fi duro niwaju ijọ fun idajọ, titi ikú olori alufa o wà li ọjọ́ wọnni: nigbana ni apania na yio pada, on o si wá si ilu rẹ̀, ati si ile rẹ̀, si ilu na lati ibiti o gbé ti salọ.

Ka pipe ipin Joṣ 20

Wo Joṣ 20:6 ni o tọ