Joṣ 22:3 YCE

3 Ẹnyin kò fi awọn arakunrin nyin silẹ lati ọjọ́ pipọ̀ wọnyi wá titi o fi di oni, ṣugbọn ẹnyin ṣe afiyesi ìlo ofin OLUWA Ọlọrun nyin.

Ka pipe ipin Joṣ 22

Wo Joṣ 22:3 ni o tọ