Joṣ 22:34 YCE

34 Awọn ọmọ Reubeni ati awọn ọmọ Gadi si sọ pẹpẹ na ni Edi: nwọn wipe, Nitori ẹrí ni li agbedemeji awa ati ẹnyin pe OLUWA on li Ọlọrun.

Ka pipe ipin Joṣ 22

Wo Joṣ 22:34 ni o tọ