Joṣ 3:14 YCE

14 O si ṣe, nigbati awọn enia ṣí kuro ninu agọ́ wọn, lati gòke Jordani, ti awọn alufa si rù apoti majẹmu wà niwaju awọn enia;

Ka pipe ipin Joṣ 3

Wo Joṣ 3:14 ni o tọ