Joṣ 9:17 YCE

17 Awọn ọmọ Israeli si dide, nwọn si dé ilu wọn ni ijọ́ kẹta. Njẹ ilu wọn ni Gibeoni, ati Kefira, ati Beerotu, ati Kiriati-jearimu.

Ka pipe ipin Joṣ 9

Wo Joṣ 9:17 ni o tọ