Mat 26:35 YCE

35 Peteru wi fun u pe, Bi o tilẹ di ati ba ọ kú, emi kò jẹ sẹ́ ọ. Gẹgẹ bẹ̃ni gbogbo awọn ọmọ-ẹhin wi pẹlu.

Ka pipe ipin Mat 26

Wo Mat 26:35 ni o tọ