Mat 26:36 YCE

36 Nigbana ni Jesu bá wọn wá si ibi kan ti a npè ni Getsemane, o si wi fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pe, Ẹ joko nihinyi nigbati mo ba lọ igbadura lọhúnyi.

Ka pipe ipin Mat 26

Wo Mat 26:36 ni o tọ