Mat 26:40 YCE

40 O si tọ̀ awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ wá, o bá wọn, nwọn nsùn, o si wi fun Peteru pe, Kinla, ẹnyin ko le bá mi ṣọ́na ni wakati kan?

Ka pipe ipin Mat 26

Wo Mat 26:40 ni o tọ