Mat 26:41 YCE

41 Ẹ mã ṣọna, ki ẹ si mã gbadura, ki ẹnyin ki o má ba bọ sinu idẹwò: lõtọ li ẹmi nfẹ ṣugbọn o ṣe alailera fun ara.

Ka pipe ipin Mat 26

Wo Mat 26:41 ni o tọ