Mat 6:13 YCE

13 Má si fà wa sinu idẹwò, ṣugbọn gbà wa lọwọ bilisi. Nitori ijọba ni tirẹ, ati agbara, ati ogo, lailai. Amin.

Ka pipe ipin Mat 6

Wo Mat 6:13 ni o tọ