Mat 6:14 YCE

14 Nitori bi ẹnyin ba fi ẹ̀ṣẹ awọn enia jì wọn, Baba nyin ti mbẹ li ọrun yio fi ẹ̀ṣẹ ti nyin jì nyin.

Ka pipe ipin Mat 6

Wo Mat 6:14 ni o tọ