Mat 9:11 YCE

11 Nigbati awọn Farisi si ri i, nwọn wi fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pe, Ẽṣe ti Olukọ nyin fi mba awọn agbowode ati awọn ẹlẹṣẹ jẹun pọ̀?

Ka pipe ipin Mat 9

Wo Mat 9:11 ni o tọ