Mat 9:12 YCE

12 Ṣugbọn nigbati Jesu gbọ́, o wi fun wọn pe, Awọn ti ara wọn le kò fẹ oniṣegun, bikoṣe awọn ti ara wọn kò da.

Ka pipe ipin Mat 9

Wo Mat 9:12 ni o tọ