Deutarónómì 10:22 BMY

22 Àádọ́rin (70) péré ni àwọn baba ńlá a yín tí ó sọ̀kalẹ̀ lọ sí Éjíbítì, ṣùgbọ́n Olúwa Ọlọ́run yín ti mú un yín pọ̀ síi ní iye bí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run.

Ka pipe ipin Deutarónómì 10

Wo Deutarónómì 10:22 ni o tọ