Deutarónómì 11:1 BMY

1 Ẹ fẹ́ràn Olúwa Ọlọ́run yín, kí ẹ sì pa ìfẹ́ rẹ̀, ìlànà rẹ̀, òfin rẹ̀ àti àṣẹ rẹ̀ mọ́ ní ìgbà gbogbo.

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:1 ni o tọ