Deutarónómì 10:6 BMY

6 (Àwọn ará Ísírẹ́lì sì gbéra láti kàǹga àwọn ará a Jákánì dé Mósérà. Níbí ni Árónì kú sí, tí a sì sin ín, Élíásárì ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ bí i àlùfáà.

Ka pipe ipin Deutarónómì 10

Wo Deutarónómì 10:6 ni o tọ