Deutarónómì 10:5 BMY

5 Mo sì sọ̀kalẹ̀ láti orí òkè náà, mo sì ki àwọn síléètì òkúta náà sínú àpótí tí mo ti kàn, bí Olúwa ti pàṣẹ fún mi, wọ́n sì wà níbẹ̀ di ìsinsin yìí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 10

Wo Deutarónómì 10:5 ni o tọ