Deutarónómì 11:12 BMY

12 Ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run yín ń mójútó ni, ojú Olúwa Ọlọ́run yín sì ń fi ìgbà gbogbo wà lórí rẹ̀, láti ìbẹ̀rẹ̀ ọdún dé òpin ọdún.

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:12 ni o tọ