Deutarónómì 11:13 BMY

13 Nítorí náà, bí ẹ bá gbọ́ràn sí àṣẹ tí mo fún un yín lónìí tọkàntọkàn: tí ẹ fẹ́ràn Olúwa Ọlọ́run yín, tí ẹ sì sìn ín, pẹ̀lú gbogbo àyà yín àti gbogbo ọkàn yín:

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:13 ni o tọ