Deutarónómì 11:14 BMY

14 nígbà náà, èmi yóò rọ òjò sórí ilẹ̀ ẹ yín lákòókò rẹ̀, àti òjò àkọ́rọ̀ àti ti àrọ̀kẹ́yìn, kí ẹ ba à lè kórè oúnjẹ yín wọlé àní wáìnì tuntun àti òróró.

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:14 ni o tọ