Deutarónómì 11:18 BMY

18 Ẹ fi gbogbo ọ̀rọ̀ mi wọ̀nyí sí àyà a yín, àti ọkàn an yín, ẹ so wọ́n bí àmì sórí ọwọ́ ọ yín, kí ẹ sì ṣo wọ́n mọ́ iwájú orí i yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:18 ni o tọ