Deutarónómì 11:19 BMY

19 Ẹ máa fí wọ́n kọ́ àwọn ọmọ yín, ẹ máa sọ̀rọ̀ nípa wọn bí ẹ bá jókòó nínú ilé, àti ní ojú ọ̀nà bí ẹ bá ń rìn lọ, bí ẹ bá sùn àti bí ẹ bá jí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:19 ni o tọ