Deutarónómì 12:14 BMY

14 Ibi tí Olúwa yóò yàn láàrin àwọn ẹ̀yà a yín nìkan ni kí ẹ ti máa rú ẹbọ yín, kí ẹ sì máa kíyèsí ohun gbogbo tí mo pàṣẹ fún un yín níbẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 12

Wo Deutarónómì 12:14 ni o tọ