Deutarónómì 13:14 BMY

14 Kí ẹ wádìí, ẹ bèèrè, kí ẹ sì tọpinpin ọ̀rọ̀ náà dájúṣáká, bí ó bá jẹ́ òtítọ́ ni, tí ó sì hàn dájú pé ìwà ìríra yìí ti ṣẹlẹ̀ láàrin yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 13

Wo Deutarónómì 13:14 ni o tọ