Deutarónómì 13:15 BMY

15 Gbogbo àwọn tí ó ń gbé ìlú náà ni kí ẹ fi idà run pátápátá. Ẹ run ún pátapáta, àti ènìyàn àti ẹran ọ̀sìn inú rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 13

Wo Deutarónómì 13:15 ni o tọ