Deutarónómì 13:18 BMY

18 Nítorí pé ẹ gbọ́ràn sí Olúwa Ọlọ́run yín, tí ẹ sì ń pa òfin rẹ̀ mọ́, tí mo ń fún un yín lónìí yìí tí ẹ sì ń ṣe ohun tí ó tọ́ lójú rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 13

Wo Deutarónómì 13:18 ni o tọ