Deutarónómì 14:1 BMY

1 Ọmọ Olúwa Ọlọ́run yín ni ẹ̀yin jẹ́: nítorí náà, ẹ má ṣe ya ara yín ní abẹ. Ẹ má ṣe gé irun iwájú orí i yín nítorí òkú.

Ka pipe ipin Deutarónómì 14

Wo Deutarónómì 14:1 ni o tọ