Deutarónómì 14:2 BMY

2 Nítorí pé ènìyàn mímọ́ ní ẹ jẹ́ fún Olúwa Ọlọ́run yín, nínú gbogbo ènìyàn tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé, Ọlọ́run ti yàn yín láti jẹ́ ìṣúra iyebíye rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 14

Wo Deutarónómì 14:2 ni o tọ