Deutarónómì 13:3 BMY

3 ẹ má fetí sí ọ̀rọ̀ tàbí àlá náà, Olúwa Ọlọ́run yín ń dán an yín wò ni, láti mọ̀ bóyá ẹ fẹ́ràn rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àyà yín àti gbogbo ọkàn an yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 13

Wo Deutarónómì 13:3 ni o tọ